Hymn 100
Ki iru awon ti of fe igbala re ki o ma wi nigbagbogbo pe: "Ki a gbe Olorun ga. ”
Meter: 7.4.7.4.5.7.4.
Scripture: OD. 70:4.
1
fOba ogo, alafia,
U no feran Re;
Ife na ki y’o dekun,
Un o sunmo 0;
N’tori O ti gbebe mi,
O ti gb’ohun mi;
O ka iwe aya mi,
O da mi n'de.
2
Fun idasile yi ni
Un o korin Re;
Gbogb’ay o okan mi ni
Un o mu fun O;
mp’Gbat’ese min ke kikan,
O da mi lare:
mf’Gba mo pe O nikoko,
O gbebe mi.
3
fGbgogb’ojo aye mi ni
Un o fi yin O;
Mo le gbe O ga ninu
Okan mi yi:
Aye wa n’nu okan mi
T'IWO y’o ma gbe!
Ayeraye kuru ju
Lati yin Q.