Hymnize

CAC Hymn Collection

Hymn 103

Gbe Oluwa ga pelu mi, ki a si jumo gbe oruko Re leke.

Meter: 8.8.8.5.

Scripture: OD. 34:3.

1

fYin Oluwa, eyin mimo

Awa ti je ni ’gbese to?

Je k’a mu gbogbo ini wa

Wa pelu ayo.

2

mfJesu l’Oko t’o daraju

O nfun wa l’okun l’oju ’ja

Ibi kan ko le de ba wa

’Gbat’ a gbekele.

3

Gbeke yin le, eyin mimo

Olododo l’Olorun wa,

Ko s’ohun to le, ya awon

T’ O fe l’odo Re.

4

mfF’ore ofe Re pa wa mo

K’a le tubo faramo O

Titi ao fi de ’nu ogo

At’ ayo l’orun.

5

’Gbana l’ao de ibi mimo

’Gbana l’a o si di mimo

Ayo nla ti a ko le so

Niy’ojetiwa.