Hymnize

CAC Hymn Collection

Hymn 106

Ewe ati agba, nwon duro niwaju ite .

Meter: P.M.

Scripture: Ifi. 20:12.

1

mfA wa fori bale fun / O Jesu,

’Wo ti s’Olori Ijo awon / eniyan Re,

Ijo ti mbe laye yi ati lo / run pelu;

Ale/luya.

2

p'Wo t’oku, t’o si jin/de fun wa,

T’o mbe lodo Baba bi Ala/gbawi wa

K'OGO at’olanla/je Tire

Ale/luya.

3

mfAti li ojo nla Pen/tikosti

Ti o ran Parakliti / si aye

Olutunu nla Re ti/ mba wa gbe;

Ale/luya

4

fLat’ ori ite Re l’o/ke orun

L’o si nwo gbogbo awon o/jise Re

T’o si nsike gbogbo awon Aje/riku Re

Ale/luya

5

fA fi iyin at’ olanla f’o/ruko Re,

pN’tori iku gbogbo awon o/jise Re,

Nigbogbo ile Yo/rubi yi:

Ale/luya