Hymn 108
A wa si nyin oruke re laelae.
Meter: 7.7.7.7.
Scripture: OD. 44:8.
1
mfF’oruk’ Olorun loke,
T’O lagbara at’ola,
Olorun ibigbogbo,
N’iyin ati ogo wa.
2
F’oruko Krist’ Oluwa,
Om’Olorun ti a bi,
Krist’ t’O da ohun gbogbo,
Ni k’a san ’yin ailopin.
3
F’Olorun Emi Mimo,
Ni k’iyin pipe wa lae,
Pelu Baba at’Omo.
Okan l’oruko, Togo.
4
Orin t’a ti ko koja,
T’ao si ma ko lae leyi;
Ki awon iran ti mbo
Dapo korin didun na.