Hymnize

CAC Hymn Collection

Hymn 110

Awon eni irapada Oluwa yio pada, won a si wa si Sioni ti awon ti orin. Ikanu ati ofo yio si fo lo.

Meter: 7.7.7.5.

Scripture: Isa. 51:11

1

fOlorun Metalokan.

Oba ile at’okun

Gbo ti wa bi a nko

Orin iyin Re

2

f’Wo imole l’owuro,

Tan ’mole Re yi wa ka

Jeki ebun rere Re,

M’aya wa bale.

3

f’Wo’ mole nigb’orun WO

K’a ri idariji gba Ki alafia

Orun F’itura fun wa.

4

fOlorun Metalokan!

Isin wa l ’aye ko to!

A nreti lati dapo

MO awon t’orun.