Hymn 112
Oluwa, iwo li o ye lati gba ogo, Ola ati agbara.
Meter: 6.6.6.8.8.
Scripture: ifi.4 :11
1
mfBaba Eleda Wa,
Af’ife gbadura;
Eni t’O fun wa ni
Ona, oto, iye;
crFi anu ro ‘jo ‘bukun Re
S’ori awa ti njosin yi.
2
mfBaba Eleda wa,
A s’okan wa paya;
Okan ominira wa,
fNyin O lopolopo;
Mi imisi Re s’okan wa,
K’ orin ‘yin wa le bu jade
3
mfBaba Eleda wa,
cr‘Wo ri iberu wa
T’o pamo l’okan wa,
pT’o nf’omije soro;
crKo wa lati gbekele O
Si mu wa la ewu yi ja
4
mfBaba Elede wa,
Je k’a f’ahon wa yin,
‘Gba t’ayo t’o jinle
Kun gbogbo okan wa;
N’nu gbogbo ayida aye,
Je k’a r’ona alafia