Hymn 113
A o si ma pe oruko Re ni Iyanu.
Meter: CM.
Scripture: Isa. 9:6
1
fOlorun Olodumare,
Baba, Omo, Emi,
Riri Eni t’a ko le mo,
Eni t’a ko le ri.
2
fYe! Baba Olodumare,
K’a wariri fun O,
Ni gbogbo orile-ede,
Li a o ma sin O.
3
fOlorun Omo, Qre wa,
p’WO t’o ra wa pada
Ma JOWO wa, Olugbala!
Gba wa patapata.
4
A! Olorun Emi Mimo,
’WO olore-ofe;
A be O, fun wa ni imo,
K’a m’Olorun n’ife.
5
fOkansoso sugbon meta,
Eni Metalokan,
Olorun awamaridi,
Eni Metalokan!