Hymnize

CAC Hymn Collection

Hymn 114

Ibukun, ati Ola, ati Ogo, ati agbara, fun eniti ojoko lori ite ati fun Odo-Agutan na lae ati laelae.

Meter: C.M

Scripture: Ifi. 5:13.

1

mfA ko ’rin s’Omo Olorun,

pOdagutan t’a pa;

Ti orun ati aye mbo,

T’O ye lati joba.

2

Si O l’awon Angeli nke,

L’ekun gbogbo orun:

p“Mimo, mimo, mim’Olorun,

T’ogo, at’om’ogun.

3

fIjo Re li aye dapo,

diLati ma kepe O;

Didan Olanla Olorun,

T’O l’agbara gbogbo.

4

Larin won ni gbogbo wa nfe

Lati yin eje Re;

Joba l’aye ati l’orun,

’Wo Omo Olorun.