Hymnize

CAC Hymn Collection

Hymn 119

Nitori ti o ti be awOn eniyan Rewo; 0 si da won ni ide

Meter: C.M

Scripture: Lk. 1:68.

1

fGbo ’gbe ayo! Oluwa de,

Jesu t’a se ’leri;

Ki gbogbo okan mura de,

K’ohun mura korin.

2

O de lati t’onde sile

L’oko eru esu,

ff’Lekun ide fo n’waju Re

Sekeseke ’rin da.

3

mfO de larin ’baje aye

Lati tan ’mole Re.

Lati mu k’awon afoju

Le foju won riran.

4

pOde,’Tunu fokan’rora,

Iwosan f’agbogbe!

crPelu ’sura or’ofe Re

Fun awon talaka.

5

fHosana, Oba alafia,

Ao kede bibo Re;

Gbogbo orun y’o ma korin

Oruko t’a feran.