Hymn 120
Ati emi, ati iyawo wipe, Ma bo
Meter: 8.7.8.8.7.7.7.7.7.
Scripture: Ifi. 22:17.
ffIwo mbo wa, Oluwa mi,
IWO mbo wa, Qba mi,
Ninu itansan ewa Re,
Ninu titayo ogo Re,
O ye k’a yo, k’a korin;
pcrO mbo ni ila orun
Awon akede npo si,
pcrO mbo: Alufa ogo;
A ko ha ngbo ago Re?
pIWO mbo wa, IWO mbo wa
A o pade Re l’ona
crA o ri O, a o mo O,
A o yin O: gbogbo okan
L’a o sipaya fun O;
fOrin ki leyi o je
Orin t’o dun rekoja;
A o tu ’fe wa jade
Si ese Re. Ologo.
mfIWO mbo wa, ni tabil’ Re,
L’awa njeri si eyi;
pT’a mo p’O npade okan wa
Ni idapo mimo julo
Eri ibukun ti mbo
crKo f’iku Re nikan han,
At’ife titobi Re;
Sugbon bibo Re pelu
T’a nfe, t’a si nduro de.
fY’o dun lati ri O njoba,
Oluwa mi, Olufe;
crKi gbogbo ahon jewo Re,
Iyin, Ola, ati ogo,
Ki won jumo fi fun O;
ff’WO Oga mi, Ore mi,
K’o segun k’o si gunwa
Titi de opin aye
Ninu ogo at’ola.