Hymnize

CAC Hymn Collection

Hymn 121

Nitoto Emi mbo kankan.

Meter: D.S.M. & Ref

Scripture: Amin Ifi. 22:20.

1

mpIjo ti nduro pe

Lati ri Oluwa,

O si wa bakan na sibe,

Ko s’alabaro fun!

Odun nyi lu Odun,

Ojo ngori ojo,

Sibe lairi Oluwa re,

O wa ninu ofo.

CHORUS

Ma bo, Jesu, ma bo.

2

mpAwon mimo l’aye,

Opo won l’oti ku;

pBi won si ti nlo l’okankan

L’a te won gbe ’ra won;

ppA te won lati sun,

Ki se l’ainireti;

crA te won lati r’eju ni,

K’ile ogo to mo,

3

Awon ota npo si,

Agbara esu nga;

Ogun ngbona, igbagbo nku,

Ife si di tutu

crY’o ti pe to! Baba,

Oloto, Olore!

’Wo ki y’okoya omije

At’ eje Ijo Re,

4

mfA nfe gbo ohun Re,

A nfe foju kan 0.

K’a le gba ade at’ogo

B’ati ngba ore Re;

fJo, wa m’ese kuro,!

At’egun at’eri,

K’o si so aye osi yi

D’aye rere Tire