Hymnize

CAC Hymn Collection

Hymn 124

Wo! Oko Iyawo n mbo, ejade LO PADE RE.

Meter: 7.6.7.6.D.

Scripture: Mat. 25:6.

1

fYo eyin onigbagbo,

Je k’imole yin tan;

Igba ale mbo tete,

Oru si fere de,

Qko iyawo dide

O fere sun mo le,

Dide, gbadura; Sora

L’oru n’igbe y’ota.

2

mpE be fitila yin wo,

F’ororo sinu Won;

E duro de ’gbala yin

Ipari ’se aye:

mfAwon oluso nwipe,

"Qko ’yawo detan

E pade Re, b’O ti mbo

Pelu orin iyin.”

3

crEyin wundia mimo,

Gbe ohun yin s’oke

fTiti n’nu orin ayo

Pelu awon Angel’

Onje iyawo setan,

Lekun na yi sile,

ffDide, arole ogo,

Oko iyawo mbo.

4

mfJesu, ’Wo ireti wa;

F’ara Re han fun wa;

’Wo orun t’a ti nreti,

Ran s’ori ile wa,

A gbe oWO wa s’oke

Oluwa je k’a ri

Ojo ’rapada aye

T’o mu wa d’odo Re