Hymnize

CAC Hymn Collection

Hymn 125

Ife gbogbo orile-ede yio si de.

Meter: 8.7.8.7.

Scripture: Hag. 2:7

1

fWa, IWO Jesu t’a nreti,

T’a bi lati da nin’de,

Gba wa l’owo ’eru at’ese,

Je k’a ri isimi Re

2

IWO n’itunu Israel’,

Ireti onigbagbo,

Ife gbogb’orile ede

Ayo okan ti nwona.

3

’Wo t’a bi lati gba wa la.

Omo ti a bi l’Oba,

Ti a bi lati joba lae,

Jeki ijoba Re de.

4

Fi Emi Mimo Re nikan

Se akoso aya wa;

Nipa ekun itoye Re,

Gbe wa sori ite Re