Hymnize

CAC Hymn Collection

Hymn 126

Eniti o ba to mi lehin kiyo rin ninu okunkun.

Meter: 7.7.8.4.

Scripture: Jn. 8:12

1

mfMole t’o da gbogbo nkan,

Ni pipe, lati n’okun,

crK’a pin, n’n’ ewa on ’bukun Re,

Wa s’odo wa.

2

f’Mole t’o joba aye,

’Mole t’o fun wa n’iye,

A! Imole t’o n s’atunda,

Wa s’odo wa.

3

pImole t’O wa s’aye

’Mole t’o nw’oju eda

ppT’o ku l’okunkun b’eniyan;

Wa s’odo wa.

4

mf’Mole t’o de ’pa ’rele

T’o tun lo s’oke giga,

T’o si wa pelu wa sibe

Wa s’odo wa.

5

mf’Mole t’o n fun wa l’oye

’Mole t’onse wa l’ewa,

Imole tin fayo simi,

Wa s’odo wa.

6

mpMase je k’ape, ari,

’Gbat’ a diju wa si O,

ppEni ti O nfi suru kan ’kun

Wole, ma bo

7

mfTire ni gbogbo ’re wa

Tiwa ni gbogbo ibi;

Jo, le won kuro lodo Re

Wa s’odo wa.

8

Mu ’se okunkun kuro;

Di wa ni ’hamora Re,

crK’arin n’nu’mole k’a ma so

Atunwa Re.

9

pAwa se O pupo ju,

crSibe, Tire l’awa se,

Je k’aye wa j’orin si O,

Wa s’odo wa.

10

Wa ninu ola-nla Re

diNi titobi ’rele Re,

ffWa, gbogbo aye nke pe O,

Wa s’odo wa.