Hymnize

CAC Hymn Collection

Hymn 129

E ma Sora, ki e si ma gbadura.

Meter: D.S.M.

Scripture: Mk. 13:33

1

mfIwo Onidajo,

A fere duro na

Pelu ayo tabi eru

Ni ’waju ite Re;

JO, pese okan wa

Fun ojo nlanla ni,

pFi emi isora kun wa

At’emi adura.

2

fK’a ma wo ona Re

L’akoko aimo ni;

Ni gbat’ Iwq sokale

Ninu olanla Re

IWO Emi aiku,

Lati da wa l’ejo

T’IWO ti ogun Baba Re

At’ ore-ofe Re

3

mfK’a le ba wa bayi,

Ni gboran soro Re

K’a ma te ’ti s’ohun ipe,

K’a ma wo ona Re,

K’a wa ipo ayo

T’awon olubukun,

K’a si sora nigba die,

Fun simi ailopin.