Hymn 130
E ma wa ninu Oluwa nigbagbogbo.
Meter: 6.6.6.6.8.8.
Scripture: Fili 4:4
1
fOluwa ni Oba,
E, bo Oluwa yin,
Eni kiku, sope,
Y'ayo ’segun titi,
ffGb’okan at’ohun yin soke
“E yo” mo si tun wi, “E yo’
2
Olugbala joba,
Olorun otito,
‘Gbat’ O we ‘se wa nu
O g’oke lo joko
3
O mbe l’odo Baba
Titi gbogbo ota
Yio teri won ba
Nipa ase Tire
4
Yo n’ireti ogo
pOnidajo mbo wa,
Lati mu ’ranse Re
Lo ’le ayeraye.
A fegbo ’hun angel nla naa
ffIpe y’odun wipe, “E yo ”