Hymnize

CAC Hymn Collection

Hymn 132

A o si ji awon oku dide li aidibaje

Meter: 8.7.8.7.8.8.7.

Scripture: I.Kor. 15:52

1

fOlorun! kini mo ri yi!

Opin de f’ohun gbogbo!

Onidajo araye yo,

O gunwa n’ite ’dajo,

ffIpe dun, iboji si tu,

Gbogbo awon oku sile,

pMura lo ko emi mi.

2

mfOku’nu Krist’ y’o ko jinde

Nigba ’pe ’keyin ba dun,

Won o lo ko l’awosanma,

Won o fi ayo yi ka;

Ko s’eru ti y’o b’okan won;

Oju Re da impoe bo

Awon ti o mura de.

3

pSugbpn elese t’on t’eru!

Ni gbigbona ’binu Re,

Won o dide, won o si ri

Pe, o se, won ko ba mo;

ppOjo ore ofe koja;

Won ngbon niwaju ’te ’dajo,

Awon ti ko mura de.

4

crOlorun, kini mo ri yi!

Opin de f ohun gbogbo,

Onidajo araye yo,

O gunwa n’ite ’dajo,

pL’ese agbelebu mo nwo,

’Gbat’ ohun gbogbo y’o koja,

crBayi ni mo nmura de.