Hymnize

CAC Hymn Collection

Hymn 133

Oluwa awon omo ogun. On na li Oba Ogo.

Meter: 8.8.8.8.7.7.6.6.8.

Scripture: OD. 24:10

1

fE gbe ori yin si oke,

Eyin ’lekun ayeraye,

Wo! Oba nla, Ologo mbo,

Lati gunwa lori ’te Re

Tani Qba ogo yi?

mpTani Qba ogo yi?

crOluwa t’O ni’pa,

Asegun l’oju ’ja,

Asegun ’joba okunkun.

2

mfE gbe ori yin si oke,

’Lekun Pearl at’ita wura,

Wo! Qba nla, Ologo mbo,

Ki keke ogun Re to de:

Tani Oba ogo na?

Tani Oba ogo na?

Oluwa ’won’m ogun

Olorun Ologo,

On li Oba ayeraye.

3

On pelu Baba at’ Emi,

Won je okan na titi lae,

Awon angeli se l’Oba,

Won nte riba n’waju’te Re

On ni Oba ogo na,

On ni Oba ogo na,

Je k’aye juba Re,

K’a si fiyin wa fun

Titi aye ainipekun.