Hymnize

CAC Hymn Collection

Hymn 139

Emi o si tun pada.

Meter: 7.7.7.7.D.

Scripture: Jn. 14:3

1

fIwo mbo wa, Oluwa;

Iwo mbo wa, Oba mi;

crNinu ’tansan ewa Re,

Ni titayo ogo Re

Mura dee, e mura dee,

Oko ’yawo fere de,

L’oru ni igbey’o ta,

Mura lo ko O, okan mi.

2

mfWundia t’o s’oloto

Ti mura nigba gbogbo

Igba ayo sun mole,

Igba awe y’odopin.

3

mfIwo mbo wa nitoto,

A o pade Re lona

A o ri O, a o mo O

N’idapo mimo julo.

4

mfWundia mewa l’ayan,

Marun pere l’o yege,

mpMarun ko ni ororo,

pIna emi n won ti ku.

5

mp’Binu Re tobi pupo

Si awon t’o gbagbe Re;

Ewure apa osi

L’a o se won nikeyin.

6

mfJowo se wa l’ayanfe,

Ki ale baO joba;

Angeli l’ao ba k’egbe

N’gba t’a ba gbe aiku wo.