Hymnize

CAC Hymn Collection

Hymn 147

E pese Okan nyin sile-

Meter: C.M.

Scripture: I Sam. 7:3

1

fJesu t’o ga julo l’orun,

Ipa Re l’o d’aye;

’Wo f’ogo nlanla Re sile,

Lati gba aye la.

2

O w’aye ninu irele

mfNi ara osi wa;

pNitori k’okan t’o rele

Le t’ipase Re la.

3

fWiwa Re ya angel’ l’enu,

Ife t’o tobi ni;

Eniyan Lanfani iye

Angeli se, ko ni.

4

fNje araye yo; sa yin de,

ffE ho iho ayo:

Igbala mbo fun elese;

Jesu, Olorun ni.

5

Oluwa, je ki bibo Re,

Nigba erinkeji,

Je ohun ti nduro de,

K’o le ba wa l’ayo.