Hymnize

CAC Hymn Collection

Hymn 150

Awa si wa lati f‘ori bale fun.

Meter: 8.7.8.7.4.7.

Scripture: Mat. 2:2

1

fEyin angel’ l’orun ogo,

To yi gbogbo aye ka;

E ti korin dida aye,

E so t’ibi Mesaiah

fE wa josin

Fun Kristi Oba titun.

2

mfEyin Oluso-agutan

Ti nso eran yin l’oru,

Imanueli wa ti de,

Irawo Omo na ntan.

3

fAmoye, f ero yin sile,

Wo ’ran didan lokere!

Wa ’reti nla orile’ de,

E ti ri irawo Re

4

mfOnigbagbo ti n teriba

Ni ’beru, at’ireti,

L’ojiji l’Oluwa o de

Ti yio mu yin re ’le.

5

A nwo b’om’owo nisi’yi,

Y’o gba ite Baba Re,

Ao ko gbogb’ aye s’odo Re,

Gbogb’ekun yo wole fun.