Hymnize

CAC Hymn Collection

Hymn 152

Oluwa joba

Meter: C.M.

Scripture: OD. 97:1

1

fAyo b’aye! Oluwa de,

K’aye gba Oba re?

crKi gbogbo okan mura de,

K’aye korin s’oke.

2

Ayo b’aye! Jesu joba,

crE je k’a ho fayo,

Gbogbo igbe, omi, oke,

Won ngberin ayo na.

3

mfK’ese on ’yonu pin l’aye,

K’egun ye hu n’ile,

O de lati mu ’bukun san,

De ’bi t’egun gbe wa.

4

O foto at’ife joba,

O jek’orile’de

Mo, ododo ijoba Re,

At’ife ’yanu Re