Hymn 154
Eje ki a lo tara si Bethlehem.
Meter: 6.6.10.5.6. & Ref.
Scripture: Lk. 2:15
1
fWa eyin olooto!
L’ayo at’isegun,
Wa ka lo, wa ka lo si Betlehem
Wa kalo woo
Qba awon Angel’
CHORUS
fE wa kalo juba Re
E wa kalo juba Re
E wa kalo juba Kristi Oluwa
2
Olodumare ni
Imole ododo,
pKo si korira inu wundia
fOlorun papa
Ti a bi, t’a ko da!
3
fAngeli, e korin
Korin itoye Re!
Ki gbogbo eda Orun si gberin,
Ogo fOlorun
L’oke orun lohun!
4
fNitoto a wole
F’Oba t’a bi loni,
Jesu IWO li awa nf ogo fun!
’Wo Omo Baba,
T’ogbearawa wo!