Hymn 156
Nigbati nwon si ri irawo na, nwon yo ayo nlanla.
Meter: 7.7.7.7.7.7.
Scripture: Mat. 2:10
1
fB ’awon ara igbani
Ti f ayo ri ’rawo na,
Bi won ti f inu didun
Tele ’mole didan re,
Be, Oluwa Olore
Ni k’a mu wa d’odo Re
2
mfBi won ti fi ayo LO
Si ibuje eran na,
Ti won si wole nibe,
F’Eni t’orun t’aye mbo,
Gege be ni k’ama yo
Lati wa site anu.
3
Bi won ti mu ore wa
Si ibuje eran na,
Be ni k’a f ayo mu wa
Ore t’ese ko baje,
Mu isura gbogbo wa
Sodo Re, Jesu Oba.
4
pJesu mimo, pa wa mo.
L’ona toro l’ojojo
cr’Gbat’ ohun aye ba pin
M’okan wa de ilu, ti
’Rawo ko nsamna mo,
’Biti won nwo ogo Re.
5
ffNi ’lu orun mimo na,
Won ko wa imole mo,
’Wo l’orun re ti ki wo,
’Wo l’ayo at’ade re,
Nibe titi l’ao ma ko
Aleluya s’Oba wa.