Hymn 159
Gbogbo ahon ni ki o ma jewo pe, Jesu Kristi ni Oluwa.
Meter: 10.8.10.8.
Scripture: Fili. 2:11
1
Omo n’bujeranl’omo Maria,
Alejo, Oluwa aye,
Omo to ru gbogbo asise wa
Ati awon abuku wa.
2
Nigbakan L’OMO Mimo julo yi
F’irele gbe’nu ayeyi;
Nisiyi gege b’Olurapada
O ni ’segun lori Ota.
3
Awon woli so asotele re;
Awon angel ri lor’ite Olugbala,
’Wo ni iyin ye fun;
Layo l’awon Tire y’o wa.