Hymn 16
Emi o ma fi otito re han lati irandiran.
Meter: L.M
Scripture: OD 89:1
1
fBaba, a sope ‘toju Re,
T’o f’alafia kun ‘le wa;
Odo Re ni won ti san wa
Owo Re l’o si ngbe won ro
2
mfOlorun, t’o ye k’a ma yin,
L’a nkepe ninu ile wa;
Oluwa orun, ti ko ko
Lati ma gbe ile aye.
3
Jek’olukuluku ‘dile
Ma kepe O tosan-toru;
K’a ko omo at’om’odo
L’ofun at’ore-ofe Re.
4
fBeni k’iran ti mbo ma so
T’ola ooko Re t’o logo,
Titi gbogbo wa y’o fi lo
Dapo mo idile t’orun