Hymnize

CAC Hymn Collection

Hymn 162

Nwon si wa logan, nwon si ri Omoo OWO na. O dubule ninu ibuje eran.

Meter: 6.6.8.6.6.8.

Scripture: Lk. 2:16

1

E yin onirele,

Ayaro, amukun,

E sare wa, mase beru;

Jesu isura wa,

T’ife Re ko n’iwon,

Ni ibuje’ ran l’ate si.

2

B’awon amoye ni

Tile f’ebun nla fun

Awon malu pelu si fun

Ni koko fun ‘busun’

Jesu gba ore won

N’itelorun n’ibujeran.

3

E yara, je k’ alo.

San gbese ’yin wa! fun;

Isin wa ni On ki yo gan;

Eni ti ife Re

Si le s’ampoa wa

S’ibuje ‘ran ti a te si.