Hymn 167
Olorun si li Oro na, Oro na si di ara.
Meter: 7.6.7.6.D.
Scripture: Jn. 1:1,14
1
mfE ji, eyin,eniyan
E ma se sun titi;
fA! Imole wa nlanla
On li o yo de yi.
Orun n’imole ara,
Jesu ni ti Okan?
Ireti awon baba
Yio hade lasan?
2
pO de k’ewon ese tu
O de k'okunkun lo;
fEyo ijoba Jesu
O ni rorun pupo,
E je k’a mu ore wa
K’a juba Oba wa
Awon amoye mu wa
A ki o mu wa bi?
3
fJe k’a fi Okan wa fun,
K’o te ’te Re sibe;
K’a fi ohun gbogbo fun
K’a si se ife Re.
ffEyo! Eyo! E tunyo!
Jesu Oluwa de
F’otosi at’oloro,
Kristi Oluwa de.