Hymn 168
Ogo ni fun Olorun loke Orun.
Meter: 7.7.7.7.
Scripture: Lk. 2:14
1
f’Gba Jehofa da aye,
cr’Gbat’ o Soro t’o.si se
Awon Angeli nkorin
ffAleluya gb’orun kan.
2
mfOrin ’yin l’a ko l’oro
Gbat’ a bi Olugbala;
crOrin’yin ni asi ko
Nigbat’ o digbekun lo.
3
p’Gbat’ aye y’o koja lo,
Iyin o gb’ojo na kan;
’Gbat’ a o d’aye titun,
Orin iyin l’a o ko.
4
Awa o ha dake bi
Titi joba na o de?
Beko! Ijo o ma ko
Orin mimo at’iyin.
5
Eniyan mimo l’aye,
fNf’ ayo korin iyin na;
Nipa ’gbagbo ni WON nko,
Bi won o ti ko l’oke.
6
Nigba emi o ba pin
Orin ni o segun ’ku;
Ninu ayo ailopin
Won o ma korin titi.