Hymn 169
Emi Mimo yio to O wa, ati agbara Oga-Ogo yio siji bo O.
Meter: 8.7.8.7.
Scripture: Lk. 1:35
1
fMawo ‘le, Jesu t’a nreti,
T’a bi lati gba ni la!
Gba wa l’ow’ese at’eru;
K’a r’isimi ninu Re.
2
mpIpa at’itunu Israel’;
Ireti awon mimo;
Olufe gbogbo orile,
Ayo okan ti nreti.
3
mfA bi 0 lati gb’eda la,
Eniyan-sugbon Olorun
Lati joba lae ninu wa,
mpMu ’joba rere Re wa.
4
mpNipa Emi Re t’o wa lae,
Nikan joba ninu wa;
Nipa ’toye Re t’o po to,
Gbe wa s’ite ogo Re