Hymn 170
Omo Alade Alafia
Meter: 7.7.7.7.
Scripture: Isa. 9:6
1
O de, Kristi Oluwa,
Lat’ ibugbe Re l’orun,
Lat’ ite alafia,
O wa si aginju wa.
2
Alade Alafia
De, lati ru ’ponju wa,
O de, lati f’imole
Le okun oru wa LO.
Meter: 7.7.7.7.
Scripture: Isa. 9:6
O de, Kristi Oluwa,
Lat’ ibugbe Re l’orun,
Lat’ ite alafia,
O wa si aginju wa.
Alade Alafia
De, lati ru ’ponju wa,
O de, lati f’imole
Le okun oru wa LO.