Hymn 172
Nigba die ewe, e o si ri mi.
Meter: D.S.M.
Scripture: Jn. 16:16
1
mpLeyin odun die,
Leyin lgba die,
diA o ko wa jo pel’awon
pTi o sun n’iboji
crOluwa, mu mi ye
Fun ojo nlanla na;
Jo, we mi ninu eje Re
pSiko ese milo.
2
mpLeyin ojo die
L’aye okunkun yi,
diA o de’bi orun ko si mo,
Ile dara dara.
3
mpLeyin iji die,
L’ebute giga yi,
diA o de b’igbi ko si mo,
Ti irumi ko si
4
mpLeyin ’yonu die,
Leyin ’pinya die,
diLeyin ise on omije,
A ki o sokun mo.
5
mfOjo ’simi die,
L’a ni tun ri l’aye,
mpA o de ibi isimi
Ti ki o pin laelae.
6
fOjo die l’o ku,
On o tun pada wa,
mfEniti O ku, k’awa le pe
K’a ba le ba joba.