Hymnize

CAC Hymn Collection

Hymn 175

Ko wa lati ma ka iye ojo wa, ki a lefi okan wa sipa Ogbon.

Meter: 8.7.8.7.

Scripture: OD. 90:12

1

mfOjo ati akoko nlo;

Won nsun wa s’eti ’boji

pAwa fere dubule na,

Ninu iho ’busun wa.

2

mfJesu ’Wo Olurapada

Ji okan t’o ku s’ese:

crJi gbogbo okan ti nto gbe

Lati yan ipo iye.

3

mpBi akoko ti nsunmo ’le,

Je k’a ro ’biti a nlo

Bi lati r’ayo ailopin,

ppTabi egbe ailopin.

4

mfAye wa nlo, iku de tan

ppJesu so wa di abo Re,

mfK’a ba O gbe, K’a ba O ku,

ppK’a ba O joba titi.

5

mpAye wan koja b’ojiji

O si nfo lo bi ’kuku,

crFun gbogbo odun t’o koja

Dariji wa, mu wa gbon.

6

mfKo wa lati ka ojo wa,

Lati ba ese wa ja,

K’a ma s’are k’a ma togbe

Tit’ao fi ri ’simi.

7

fGbogbo wa fere duro na

Niwaju ite ’dajo

ffJesu ’w o t’o segun iku

Fi wa s’apa Otun Re.

8

mfAy wa nlo, iku de tan

ppOlugbala, pa wa mo,

K’a ba O gbe, k’a ba O ku

fK’a ba O joba titi.