Hymnize

CAC Hymn Collection

Hymn 177

Nje Oluwa niyio ma se Olorun mi.

Meter: C.M.

Scripture: Gen. 28:21

1

mfOllorun Betel’ eni ti

O mbo awon Tire,

Enit’ o mu baba wa la

Ojo aye won ja

2

pA mu eje at’ebe wa

Wa iwaju ‘te Re,

Olorun awon baba wa

fMa je Olorun wa

3

Ninu idamu aye yi

Ma to isise wa,

Fun wa ni onje ojo wa

At’aso t’o ye wa.

4

Na ojiji’ ye Re bo wa

Tit’ajo wa opin

Ati ni ’bugbe Baba wa,

Okan wa o simi.

5

Iru ibukun bi eyi

L’a mbere L’OWO Re,

Iwo o je Olorun wa.

At’ipin wa laelae.