Hymn 181
Je ki ise Re ki o han si awon Omo-odo Re.
Meter: C.M.
Scripture: OD. 90:16
1
mfOlorun at’ ireti mi,
Oro Re l’onje mi,
Owo Re gbe mi ro l’ewe
Ati l’odomode.
2
Sibe mo nrohun iyanu
T’O nseni ododun;
Mo fi ojo mi ti o ku
S’iso Tire nikan.
3
Ma ko mi, nigba ’gbara ye,
Ti ewu baba mi,
ffKi ogo Re ran yi mi ka
Nigbati mo ba ku.