Hymnize

CAC Hymn Collection

Hymn 184

Mu mi mo ona ti emi iba ma to.

Meter: CM

Scripture: OD. 143:8

1

mfOluwa fi apa Re han,

Si jek’ ar’ogo Re,

Ki gbogbo wa ri ami Re,

K’o m’ okan lile TO.

2

diK’aanu yo wa ninu ebi,

Gbogb’ ese t’a ti da,

Ki odun ti a bere yi,

Le pari pelu Re.

3

pRan Emi Re lat’ oke wa,

K’alefe O julo,

K’elese ti o n’ife ri,

Le ko lati feni.

4

mpNigbat’ a ba de ’waju Re,

N’ ile ayeraye,

fKi opo d’ipo wa nihin,

Lati f iyin fun O.