Hymn 187
Igba mi mbe li OWO re.
Meter: 7.7.7.7.
Scripture: OD. 31:15
1
mfAlakoso ti orun,
Alanu at’Ologbon;
Igba mi mbe l’ OWO Re,
Opin gbogbo l’ase Re.
2
Ase Re l’oda aye
Ati ibi mi pelu,
Obi, ile, on igba
Nipa Re ni gbogbo won.
3
pIgb’ aisan on ilera,
Igba ise on oro,
Igba ’danwo, ibinu,
Igba ’segun, iranwo.
4
Igba iridi Esu,
Igba ’to ’fe Jesu wo,
Won o wa, won o si LO,
B’ore wa orun ti fe.
5
ffIwo Olore-ofe,
’WO ni mo f’emi mi fun,
Emi jewo ife Re,
Emi teriba fun O