Hymnize

CAC Hymn Collection

Hymn 188

Eyipada kuro ninu ona buburu nyin; nitori kini eyin o seku.

Meter: 7.7.7.7.D.

Scripture: Esek. 33:11

1

mpElese, e yipada,

Ese ti e o fi ku?

Eleda yin ni mbere

Tofeki e ba On gbe;

Oran nla ni O mbi yin,

Ise owo Re ni yin;

crA! eyin alailope

Ese t’ e o ko ’fe Re?

2

pElese e yi pada,

Ese ti o o fi ku?

Olugbala ni mbere;

Eni t’O gb’emi yin la;

Iku Re y’o j’asan bi?

E o tun kan mo ’gi bi?

diEni ’rapada ese

Te o gan or’ofe Re?

3

pElese, e yi pada,

Ese ti e o fi ku?

Emi mimo ni mbere

Ti nfojo gbogbo ro yin;

E ki o ha gb’ore Re?

E o ko iye sibe?

diAti nwa yin pe, ese

T’ e mbi Olorun ninu?

4

crIyemeji ha nse yin

Pe ife ni Olorun

E ki o ha gboro Re?

K’e gba ileri Re gbo?

pW’Oluwa lodo yin,

ppJesu sun, w’omije Re;

Eje Re pelu nke pe:

Ese ti e o fi ku?