Hymn 189
Nitori ti Oluwa mbo wa se idajo aye
Meter: 6.5.9.14.9. & Ref.
Scripture: OD. 96:13
1
mfOjo nla kan mbo wa,
OJO nla kan mbo;
Ojo nla kan mbo wa, nigbose,
T’awon eniyan mimo at’elese y’o pinya,
Iwo ha setan fun ojo na?
CHORUS
crO ha setan? O ha se tan?
O setan fun ojo idajo?
O ha setan? O ha setan?
Fun OJO ’dajo.
2
fOJO didan kan mbo
Ojo na mbo wa,
ffOjo didan ’kan mbo, nigbose,
Sugbon didan re je ti awon t’o fe Oluwa
IWO ha se tan fun ojo na?
3
pOJO ’banuje mbo,
OJO na mbo wa,
OJO ’banuje mbo nigbose
Ti elese y’o gbo pe: LO, Emi ko mo yin ri’
IWO ha setan fun ojo na?