Hymn 190
Nitoriti O mbo wa se idajo aye.
Meter: 8.8.8.
Scripture: I Kro. 16:33
1
mfOjo ’binu, ojo aro;
T asotele Woli ni se,
Ti orun at’ aye njona.
2
fIro iyanu, fere dun
Ja gbogbo iboji aye;
Gbogbo eda wa ’waju Re.
3
crOro ti mbe ninu ’wena,
pA ko Won sile lesese;
Lati fi ’dajo f’eniyan.
4
fIkede, ’rokeke b’aye,
Won ji kuro n’nu orun won
Lati je ’pe Onidajo.
5
mfOnidajo ododo nla!
crFun mi l’ebun ’dariji Re,
pK’ojo esan to de ba mi.