Hymnize

CAC Hymn Collection

Hymn 192

Nitori ailabawon li ebun ati ipe Olorun.

Meter: 11.11.11.9 & Ref.

Scripture: Rom 11:29

1

fIpe t’o ni 'bukunl’aoke orun

Ipe t’o ni ‘bukun li emi npe wa,

O fi agbara fun eni ti n sare

Eni t’o ba gbagbo, fun 0 ni.

CHORUS

ffFun o ni ara fun O ni.

Gbekele 'leri Re to daju (ara mi)

FUN o ni, ma, fun o ni

Eni t’o ba gbogbo, fun o ni.

2

mpO ti f’eje Re ‘yebiye se ‘laja

Omo Olorun ti sise igbala

Gbogbo ise naa ti pari, o pari

mfLati gba 'bukun na, fun o ni.

3

Y’o gba enl t’o ba gbagbo la d’opin,

Otito Olorun ti sise igbala

Gbogbo ise na ti pari, o pari

mfEni t’o ba gbagbo, fun o ni

4

mpMa siyemeji mo, wa’ do Re loni,

mfKuro ninu ese re patapata

‘Tori anu Re nla, y’o dariji o,

Y’o si s’amona re de orun

5

mpLohun ni ‘le ogo ao korin ‘yin Re,

mfLi ohun isegun; lae ati lae,

B’ipe na tile pe, sibe titun ni,

ffOgo, Aleluya, fun o ni