Hymn 198
Jesu ti Nasareti li o nkoja
Meter: 8.8.8.8.8.9.8.9.
Scripture: Lk. 18:37
fE redi irokeke yi
Ti eniyan ti nwo koja?
’ Jojumo n’iwojopo na,
Eredi re, ti won nse be?
fWon dahun Fohun jeje Pe
di“Jesu ti Nasareti l’O nkoja.
mfTani Jesu? Ese ti On
Fi nmi gbogbo ilu bayi?
Ajeji Ologbon ni bi?
Ti gbogb’ eniyan nto leyin?
pWon dahun l’ohun jeje pe
cr“Jesu ti Nasaret’ l’O nkoja”.
Jesu On na l’O ti koja
pOna irora wa l’aye
’Bikibi t’On ba de, won nko
Orisi arun wa ’do Re
fAfoju yo, b’o ti gbo pe;
cr“Jesu ti Nasaret’ l’O nkoja.”
On si tun de! n’ibikibi
Ni awa si nri ’pase Re,
On nrekoja l’ojude wa
O wole lati ba wa gbe,
fKo ha ye k’a fayo ke pe
di“Jesu ti Nasaret’ l’O nkoja.
Ha! e wa, eyin t’orun wo!
fGba ’dariji at’ itunu,
pEyin ti e ti sako lo
crPada gba or’ofe Baba,
Eyin t’a-danwo abo mbe
f“Jesu ti Nasaret’ l’O nkoja”
pSugbon b’iwo ko ipe yi,
crTi o si gan ife nla Re;
On yio peyinda si o,
Yio si ko adura re;
p“Opeju” n’igbenay’o je
pp“Jesu ti Nasaret’ ti koja”