Hymnize

CAC Hymn Collection

Hymn 202

Enikeni ti o ba sife, ki o gba omi iye na lo fe

Meter: 8.7.8.7.11.

Scripture: Ifi- 22:17

1

mfO tosi elese, e wa,

Wa ni wakati anu,

Jesu setan lati gba yin,

O kun f anu at’ife.

crO si le, se O mura tan, ma foya.

2

mfEyin alaini, e wa gba

Ogo Olorun l’ofe

Gbagbo toto, ronu toto

Or’ofe ti o nfa wa

crWa ’do Jesu laini owo, sa wa ra.

3

mpMa je k’okan yin da yin ro,

Mase ro ti aye yin,

Gbogbo yiye t’O mbere ni

Ki e sa mo aini yin

crEyi to fun yin bi ’mole lokan yin.

4

mpEyin f eru npa, fare mu

Te sonu te si segbe

Bi e duro tit’e o san

E ki yoo wa rara;

crF’elese ni, On ko wa f’olododo.

5

mfOlorun goke l’awo wa;

O nfi eje Re bebe,

crGbe ara le patapata,

Ma gbekele ohun mi,

fJesu nikan l’O le s’elese l’ore.

6

ffAngeli at’awon mimo

Nkorin ’yin Od’agutan;

Gbohungbohun oruko Re

Si gba gbogbo orun kan,

Aleluya! elese le gberin na.