Hymn 204
E wa nitori ohun gbogbo fetan.
Meter: L.M.
Scripture: Lk. 14:17
1
fE lese, gba ’hinrere gbo!
Wa si ase Oluwa mi,
Gbo, k’o si m’ojo ore re,
Ohun gbogbo set an, ma bo!
2
fBaba mura tan lati gba
Awon ’mo Re t’o pada wa;
Olugbala re mura tan,
O na ’wo ogbe Re si O.
3
Emi ife Re mura tan
Lati m’okan lile kuro,
Lati feje na s’eleri,
K’a we O, k’a so o d’omo.
4
fAwon angeli mura tan,
Lati y’ayo ibukun re;
Won y’o fi duru korin ’yin
Ore-efe irapada.
5
fBaba, Omo, Emi Mimo
Mura pelu om’ogun Re
crGbogbo orun y’o si ho pe,
Oku ye, a ri eni nu!