Hymn 207
Filipi SO fun pe, “Wa wo O”.
Meter: 11.11.11.7. & Ref.
Scripture: Jn. 1:46
1
mfIpe ihinrere na ni yi, Wa wo,
Fun gbogbo orile ede ni,
Wa wo, Jesu mu igbala ofe wa,
Wa wo, Ohun ti O se fun mi.
CHORUS
fWa wo, wa wo,
Ohun ti O se fun mi
crO r’okan mi n’nu ese
O si we mi mo toto,
mfEyi ni O se fun mi.
2
Oun ki yoo tan o je laelae, wa wo,
Y’o gba o ninu wahala re gbogbo,
crO nduro lati tewo gba o wa wo
Gbogb’ ohun to se fun mi.
3
fWa f’Olugbala se igbekele re,
Tete sa si abe abo Re, wa wo
mpNinu anu Re ni k’o ma gbe,wa wo
Ohun ti O se fun mi.