Hymn 209
Eje Jesu Kristi Omo Re ni nwe wa nu kuro ninu ese gbogbo.
Meter: 7.6.7.6.D. & Ref.
Scripture: I Jn. 1:7
1
mfIsun ’wenumo kan mbe
crLati oke Kalfari,
Oluwa si isun na
mfFun gbogbo elese,
Nisiyi ohun re npe
Lati SO d’ominira
fE wa fun iwenumo
crNibi ite-anu.
CHORUS
pIsun ti nsan ni Kalfari
Isun Kalfari na nsan
crLofe lo nsan, fun gbogbo wani
Isun Kalfari na nsan.
2
mpBi eru ese npao
Ti are si mu o,
Agbara mbe n’isun na,
Wa we n’nu isun na.
mfIwosan mbe ninu re
Pelu iwenumo,
Omi anu nsan titi
Lat’ oke Kalfari.
3
mfOrisun iye n’ise,
Lofe l’o nsan fun wa,
mpBere, we ki o si mo,
Si gba omnira re,
fGba Kristi l’Oluwa re
Y’o SO o di kanga
Alafia at’ayo
Y’o ma san ninu re.