Hymn 214
E wa sodo mi gbogbo enyin ti nsise, ti a si di eru wuwo le lori Emi o si fi isimi fun nyin.
Meter: 9.9.9.6.D.
Scripture: Mat. 11:28
1
mfW a s’odo Jesu, mase duro;
L’oro Re l’o ti fona han wa,
Oduro li arin wa loni,
Onwi pele pe, wa!
CHORUS
crIpade wa yio je ayo,
Gb’okan wa ba bo L’OWO ese.
T’a o si wa pelu Re,
Jesu, N’ile ayeraye!
2
fJek’omode wa! E gb’ohun Re;
Jek’okan gbogbo kun fun ayo,
K’a si yan Jesu l’ayanfe wa,
Ema duro, e wa.
3
mfRanti p’O wa pelu wa loni,
F’ eti s’ofin Re, k’o si pamo;
crGbo b’ohun Re ti nwi pele pe
Eyin omo Mi wa. .