Hymn 218
Nitori bayi li Oluwa wi fun ile Isreali, e wa mi, enyin o si ye.
Meter: 8.7.8.7.4.7.
Scripture: Amo. 5:4
1
mfElese o ha gan ise
T’afanu ran lat’ oke;
Ohun jeje l’o fi ranse
Oro Re kun fun ife;
Te ti lele,
Ise Re kun fun ife
2
fGbo awon ojise rere,
Won nj’ise Oba Sion;
“Idariji fun elese
L’ofe l’oruko Jesu”
crBotipoto.
p’Dariji l’oruko Re.
3
fF’okan itanje at’eru
Won mu ’bale aya wa,
Won wa fi ise itunu,
Le omije yin kuro;
pOjise ’re,
ppNu omije nu kuro.
4
mfTani ti gba ihin wa gbo?
Tani gb’oro ayo na?
T’o gba ihin ’dariji mu
Ti Oluwa na si yin?
E ha le gan
Ore anu Oluwa.