Hymnize

CAC Hymn Collection

Hymn 22

Ba wa duro: nitori o di ojo ale.

Meter: 10.10.10.10

Scripture: Lk 24:29

1

mfWabami gbe, ale fere le tan;

Okunkun nsu, Oluwa ba mi gbe

Bi Oluranlowo, miran ba ye,

Iranwo alaini, Wa ba mi gbe.

2

pOjo aye mi nsare lo s’opin

Ayo aye nku, ogo re nwomi,

Ayida at’ibaje ni mo n ri,

cr‘Wo ti ki yipada, wa ba mi gbe.

3

mpMa wa l’eru b’Oba awon oba

B’oninure, wa pelu ‘wosan Re,

Ki O si ma kanu fun egbe mi,

Wa, Ore elese, wa ba mi gbe.

4

Mo n fe O ri, ni wakati gbogbo

Kilo le segun esu b’ore Re?

Tal’o le se amona mi bi Re?

N’nu ‘banuje at’ayo ba mi gbe.

5

mfPelu ‘bukun Re, eru ko ba mi

Ibi ko wuwo, ekun ko koro,

FOro iku da? Segun isa da?

Un o segun sibe, b’Iwo ba mi gbe

6

pWa ba mi gbe, ni wakati iku,

CrSe ‘mole mi si toka si orun

FB’aye ti nkoja, k’ile orun mo,

Fp.mpNi yiye, ni kiju, wa ba mi gbe.