Hymn 222
E jeki a se lala lati WO inu isimi na.
Meter: S.M.
Scripture: Heb. 4:11
1
mfN ibo n’isimi wa
’Simi f okan are?
Lasan l’a wa s’opin okun,
Ati s’ opin ile.
2
Aye ko le fun ni
N’isimi ti a nfe;
K’a le pe titi laye ko!
pK’a si tete ku ko!
3
Aye kan mbe loke
T’o jinna s’ aye yi,
Won ko nsiro odun nibe;
Ife ni aye na!
4
pIku mbe, apa re
Kawo’emi wa yi;
ppB’ irora kikoro ti to
crNinu iku keji!
5
fOlorun jo ko wa
pK’a sa fun iku yi;
K’a ma ba le wa lodo Re,
K’a si segbe laelae.
6
Nihin l’ebe wa mo!
Aye ife pipe,
Ati isimi ailopin
Wa ninu Re nikan.